Below are the names of some animals in yoruba and their english meaning.
Aaka = Hedgehog
Àgbọnrín = Deer
Agemon, ògà = Chameleon
Agodongbo = Colt
Àgùnfọn = Giraffe
Àkeke = Scorpion
Àkókó = Wood pecker
Akò = Grey Heron
Aparo = Bushfowl
Àwòdì, Àṣá = Kite
Ẹfọn = Buffalo
Ẹ̀ga = Weaver
Erè, Òjòlá = Python
Erin = Elephant
Erinmi = Hippopotamus
Ẹtà = civet cat
Ẹtù, Awó = Guinea fowl
Etu, Èsúró = Duiker
Ewúrẹ = Goat
Rakunmi = camel
Ìbákà = Canary bird
Ìgalà = Bushbuck
Ìjàpá, Ahun, Alábahun = Tortoise
Ìnọkí = Baboon or Mandrill
Ìràwò = Beetle
Kọlọkọlọ = Fox
Kìnìún = Lion
lámilámi = Dragonfly
Ofàfà = Tree hyrax
Ọ̀bọ = Monkey
Ológbò = Cat
Omo-nlé = Gecko Lizard
Òtòlò = Waterbuck
Òwìwí = Owl
Oyà = cane Rat/Grasscutter
Pẹpẹyẹ = Duck
Yànmùyánmú, ẹfọn = Mosquito
Eranko bi imado/Àgbánréré = Rhinoceros
Ẹkùn/Ògìdán = Tiger
Àmọ̀tẹ́kùn = Leopard
Erinmi/Erinmilokun = Hippopotamus
Ìmàdò = Wild boar
Ikõkò = Hyena/Hyaena
Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ = Donkey
Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ abilà = Zebra
Ìjímèrè = Brown Monkey
Egbin/Ẹtu/Olube/Esuró = Antelope
Ọ̀wàwà = Cheetah
Ọṣà = Chimpanzee
Ọka = Gabon viper
Sebe = Cobra
Ahọnrihọn = Alligator
Antaa/Aleegba = Monitor Lizard
Igun, Gunnugun, Gurugu, Akala = Vulture
Ologiri = Palm bird
Arigiṣẹgi = Wood- Carrier
Ọkin = Peacock
Ọkẹrẹ = Squirrel
Okinrin = Okinrin
Okete = Pouch Rat
Edu = Wild Goat
Akurakuda = Shark
Ekolo = Earthworm
Ẹyẹ-Orin = Songbird
Aparo = Partridge
Ibakasiẹ = Ass
Ẹyẹ-Ofu = Pelican
Osin = Water Bird
Yanja-yanja = Sea Bird
Adaba = Dove
Paramọlẹ = Viper
Pẹju-pẹju = Seagulls
Sọmidọlọti/Oloyo = Yellow-haired Monkey
Ẹyẹ-Iwo = Raven
Iṣawuru = Fresh-water Snail
Igbin/Aginniṣọ = Snail
Ẹdun = Ape
Alangba = Lizard
Alakasa = Lobster
Ere = African rock python
Ẹlẹdẹ-Igbo = Boar
Elegbede = Chimpanzee
Ojola = African rock Python
Kọnkọ = frog
Ọpọlọ = Toad
Eegbọn = Tick/flee
Akan = Crab
Oriri = Wild pigeon
Oorẹ, Eerẹ, Ojigbọn = Porcupine
Tanpẹpẹ = Blank-ants
Ọkunrun = Millipede
Aja-Ọdẹ = Hound
Lekeleke = Cattle-egret
Ogongo = Ostrich
Ikan, Ikamudu = White ant/Termite
Idi = Eagle
Oyin = Bee
Eṣinṣin/Eṣin = Housefly
Kokoro-Ojuọti = Gnats
Eliri = Mouse
Abonilejọpọn = Red-ants
Ina-Ori = Lice
Idun = Bedbugs
Alapandẹdẹ = Swallow
Iru, Eṣinṣin- Nla = Gadfly
Akata/Ajako = Jackal
Eja-odo = Jelly fish
Aferegbojo/ Afe-imojo = A species of bird
Elulu = A brown feathered bird
Labalaba = Butterfly
Add yours!!!
We are on Instagram @viraltrendnews